Esther AJAYI@adexdainty92
ṢÀWÁRÍ ÀṢÌṢE NÁÀ 🔍 | Spot the bug in 10s!
O ya, dán ojú rẹ wò! 👀
Àṣìṣe kan wà nínú kóòdù yìí tí ó lè ba gbogbo layout jẹ́.
🚨 Kí ni àṣìṣe náà?
Line 1, 2, 3, tàbí 4?
Kọ ìdáhùn rẹ sínu comments ni kíákíá! 👇🏽
#KooduPeluEsther #CodingChallenge #HTMLTips #LearnHTML
01225






